ṣẹ

See also: Appendix:Variations of "se"

Yoruba

Pronunciation

  • (high-tone): IPA(key): /ʃɛ́/
  • (mid-tone): IPA(key): /ʃɛ̄/
  • (low-tone): IPA(key): /ʃɛ̀/

Verb

ṣẹ́

  1. to break; to snap
    Synonyms: fọ́,
  2. to sprain
    Synonym: rọ́
    Ó fẹsẹ̀ ṣẹ́He sprained his leg
  3. to fold
    Synonym:
  4. to gush out; to teem out
    Ikán ń ṣẹ́ láti ilẹ̀ sísánTermites are teeming from the cracked earth
  5. (with èpè (swear; curse)) to curse; to swear
    Ọmọlúwàbí kò gbọdọ̀ ṣẹ́ èpèA good person mustn't spew curses
Derived terms
  • ṣẹ́gun (to triumph; to win a war)
  • ṣẹ́lẹ̀rú (creek; stream)
  • ṣépè (to swear)

Verb

ṣẹ́

  1. to thatch
    Synonym: bọ̀
    Wọ́n máa ń tún ààfin Ọ̀yọ́ ṣẹ́ lọ́dọọdún BẹẹrẹThe palace of Oyo is rethatched every Beere festival

Verb

ṣẹ́

  1. to be poverty-stricken; to be destitute
    Ìṣẹ́ ti ṣẹ́ ọ̀tá wa.Poverty has afflicted our enemies.
Derived terms

Verb

ṣẹ̀

  1. to offend
    O ti ṣẹ̀ wá, o dẹ̀ ti já wa kulẹ̀.You have done us wrong and let us down.
  2. to sin
Derived terms
  • dẹ́ṣẹ̀ (to sin)
  • ẹ̀ṣẹ̀ (offence; sin)

Verb

ṣẹ

  1. to happen
  2. to manifest; to come to pass
    A ò tíì kófá nílẹ̀, gbogbo ẹ̀ ti ń ṣẹ.We haven't packed the Ifa divination paraphernalia from the ground, and everything's already manifesting.
Derived terms

Verb

ṣẹ̀

  1. to originate from; to emerge from
    Ibo ni wọ́n ti ṣẹ̀?Where do they originate from?
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.