yimiyimi

Yoruba

Yímíyímí ń yí ìṣù imí pẹ̀lú ẹsẹ̀ ẹ̀yìn rẹ̀

Etymology

Reduplication of yímí (to roll dung), literally "That which rolls dung".

Pronunciation

  • IPA(key): /jí.mĩ́.jí.mĩ́/

Noun

yímíyímí

  1. dung beetle
    Synonym: ayíkúlè
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.