jẹun

See also: jeun

Yoruba

Etymology

From jẹ (to eat) + ohun (thing).

Pronunciation

  • IPA(key): /d͡ʒɛ̄.ũ̄/

Verb

jẹun

  1. to eat food
    Màá ṣiṣẹ́ tán kí n tó jẹun ọ̀sán lénìí.I'll finish the work before I eat lunch today.
  2. to make a living
    Synonym: gbọ́ bùkátà
    Kí ni wọ́n ń ṣe jẹun?What do they do for a living?

Derived terms

  • jẹun sápò
  • jẹun síkùn
  • jẹun sókè
  • jíjẹun (eating)
  • ọ̀jẹun (eater)
  • àtijẹun (eating)
  • àwòdì jẹun èpè sanra
  • ìjẹun (eating; dining)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.