fawẹli
Yoruba
Alternative forms
- fáwẹ́ẹ̀lì
Pronunciation
- IPA(key): /fá.wɛ̀.lì/
Noun
fáwẹ̀lì
- vowel
- Fáwẹ̀lì méjìlá l'ó wà ní èdè Yorùbá. Fáwẹ̀lì àìránmúpè méje: A, E, Ẹ, I, O, Ọ, U, àti fáwẹ̀lì àránmúpè márùn-ún: AN, ẸN, IN, ỌN, UN.
- In Yoruba, there are 12 vowels. 7 oral vowels: A, E, Ẹ, I, O, Ọ, U, and 5 nasal vowels: AN, ẸN, IN, ỌN, UN.
Derived terms
- fáwẹ̀lì ẹlẹ́yọ̀ọ́ (“diphthong”)
- fáwẹ̀lì ẹ̀bádò (“open-mid vowel”)
- fáwẹ̀lì ẹ̀bákè (“close-mid vowel”)
- fáwẹ̀lì ẹ̀yìn (“back vowel”)
- fáwẹ̀lì iwájú (“front vowel”)
- fáwẹ̀lì odò (“low vowel”)
- fáwẹ̀lì àhánudíẹ̀pè (“close-mid vowel”)
- fáwẹ̀lì àhánupè (“close vowel”)
- fáwẹ̀lì àránmúpè (“nasal vowel”)
- fáwẹ̀lì àyanudíẹ̀pè (“open-mid vowel”)
- fáwẹ̀lì àyanupè (“back vowel”)
- fáwẹ̀lì àárín (“mid vowel”)
- fáwẹ̀lì àìránmúpè (“oral vowel”)
- fáwẹ̀lì òkè (“high vowel”)
- àdàmọ̀dì-fáwẹ̀lì (“semi-vowel”)
- àwítúnwí fáwẹ̀lì (“assonance”)
- àǹkóò fáwẹ̀lì (“vowel harmony”)
- ìyọ́pọ̀ fáwẹ̀lì (“vowel coalescence”)
See also
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.