aṣọle

Yoruba

Aṣọ́lé tó ń mú bọ́ọ̀lù.

Etymology

  • a- (agent prefix) + ṣọ́ (to guard) + ilé (home; base), literally guard of the base.

Pronunciation

  • IPA(key): /ā.ʃɔ́.lé/

Noun

aṣọ́lé

  1. (soccer) goalkeeper
    Synonym: golí
    • 2019 July 27, “Vincent Enyeama: Aṣọ́lé Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí ṣe tán láti padà sórí pápá. [Vincent Enyema: A former Nigerian goalkeeper is ready to return to the pitch.]”, in BBC Yorùbá:

Derived terms

  • gbá gorí aṣọ́lé (to lob)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.