ọkọ ofuurufu

Yoruba

Ọkọ̀ òfuurufú tí ń fò

Etymology

From ọkọ̀ (vehicle) + òfuurufú (sky).

Pronunciation

IPA(key): /ɔ̄.kɔ̀ ò.fūū.ɾū.fú/

Noun

ọkọ̀ òfuurufú

  1. airplane
    Synonym: bààlúù
  2. aircraft

Derived terms

  • awakọ̀ òfuurufú (pilot)
  • ibùdókọ̀ òfuurufú (airport)
  • pápákọ̀ òfuurufú (airfield; airport)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.